Ẹ́kísódù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+ Àìsáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+
2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+
22 Torí Jèhófà ni Onídàájọ́ wa,+Jèhófà ni Afúnnilófin wa,+Jèhófà ni Ọba wa;+Òun ni Ẹni tó máa gbà wá.+