Sáàmù 74:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Rántí àwọn èèyàn* tí o ti yàn tipẹ́tipẹ́,+Ẹ̀yà tí o rà pa dà láti fi ṣe ogún rẹ.+ Rántí Òkè Síónì, ibi tí o gbé.+ Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+ Sáàmù 135:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ìyìn ni fún Jèhófà láti Síónì,+Ẹni tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù.+ Ẹ yin Jáà!+
2 Rántí àwọn èèyàn* tí o ti yàn tipẹ́tipẹ́,+Ẹ̀yà tí o rà pa dà láti fi ṣe ogún rẹ.+ Rántí Òkè Síónì, ibi tí o gbé.+