Sáàmù 44:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,+Kì í sì í ṣe apá wọn ló mú kí wọ́n ṣẹ́gun.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti apá rẹ+ àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ ló ṣe é,Nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.+
3 Kì í ṣe idà wọn ni wọ́n fi gba ilẹ̀ náà,+Kì í sì í ṣe apá wọn ló mú kí wọ́n ṣẹ́gun.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti apá rẹ+ àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ ló ṣe é,Nítorí pé inú rẹ dùn sí wọn.+