Sáàmù 74:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 74 Ọlọ́run, kí ló dé tí o fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?+ Kí nìdí tí ìbínú rẹ fi ń jó bí iná* lórí agbo ẹran tó wà ní ibi ìjẹko rẹ?+ Sáàmù 95:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+ Sáàmù 100:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+
74 Ọlọ́run, kí ló dé tí o fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?+ Kí nìdí tí ìbínú rẹ fi ń jó bí iná* lórí agbo ẹran tó wà ní ibi ìjẹko rẹ?+
7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+ Sáàmù 100:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+
3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+