Diutarónómì 33:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò láti ìgbà àtijọ́,+Ọwọ́ ayérayé rẹ̀ wà lábẹ́ rẹ.+ Ó máa lé ọ̀tá kúrò níwájú rẹ,+Ó sì máa sọ pé, ‘Pa wọ́n run!’+ Sáàmù 91:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 91 Ẹni tó bá ń gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ+Yóò máa gbé lábẹ́ òjìji Olódùmarè.+
27 Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò láti ìgbà àtijọ́,+Ọwọ́ ayérayé rẹ̀ wà lábẹ́ rẹ.+ Ó máa lé ọ̀tá kúrò níwájú rẹ,+Ó sì máa sọ pé, ‘Pa wọ́n run!’+ Sáàmù 91:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 91 Ẹni tó bá ń gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ+Yóò máa gbé lábẹ́ òjìji Olódùmarè.+