ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 127:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 127 Bí Jèhófà ò bá kọ́ ilé,

      Lásán ni àwọn tó ń kọ́ ọ ṣiṣẹ́ kára lórí rẹ̀.+

      Bí Jèhófà ò bá ṣọ́ ìlú,+

      Lásán ni ẹ̀ṣọ́ wà lójúfò.

  • Òwe 16:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Fi gbogbo ohun tí o bá ń ṣe lé Jèhófà lọ́wọ́,*+

      Ohun tí o fẹ́ ṣe á sì yọrí sí rere.

  • Àìsáyà 26:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Jèhófà, o máa fún wa ní àlàáfíà,+

      Torí pé gbogbo ohun tí a ṣe,

      Ìwọ lo bá wa ṣe é.

  • 1 Kọ́ríńtì 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 tó fi jẹ́ pé kì í ṣe ẹni tó ń gbìn ló ṣe pàtàkì tàbí ẹni tó ń bomi rin, bí kò ṣe Ọlọ́run tó ń mú kó dàgbà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́