ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 19:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ní àárọ̀ ọjọ́ kẹta, ààrá sán, mànàmáná kọ. Àwọsánmà ṣú+ bo orí òkè, ìró ìwo sì dún sókè gan-an, ẹ̀rù wá ń ba gbogbo àwọn tó wà nínú àgọ́.+

  • Ẹ́kísódù 19:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+

  • Sáàmù 77:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ìró ààrá rẹ+ dà bí ìró àgbá kẹ̀kẹ́ ẹṣin;

      Mànàmáná tó ń kọ mú kí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé* mọ́lẹ̀;+

      Ayé mì tìtì, ó sì mì jìgìjìgì.+

  • Sáàmù 104:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ó wo ayé, ayé sì mì tìtì;

      Ó fọwọ́ kan àwọn òkè, wọ́n sì rú èéfín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́