Sáàmù 78:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 A ò ní fi wọ́n pa mọ́ fún àwọn ọmọ wọn;A ó ròyìn fún ìran tó ń bọ̀+Nípa àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ fún ìyìn àti nípa agbára rẹ̀,+Àwọn ohun àgbàyanu tó ti ṣe.+ Róòmù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí gbogbo ohun tí a kọ ní ìṣáájú ni a kọ fún wa láti gba ẹ̀kọ́,+ kí a lè ní ìrètí+ nípasẹ̀ ìfaradà+ wa àti nípasẹ̀ ìtùnú látinú Ìwé Mímọ́.
4 A ò ní fi wọ́n pa mọ́ fún àwọn ọmọ wọn;A ó ròyìn fún ìran tó ń bọ̀+Nípa àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ fún ìyìn àti nípa agbára rẹ̀,+Àwọn ohun àgbàyanu tó ti ṣe.+
4 Nítorí gbogbo ohun tí a kọ ní ìṣáájú ni a kọ fún wa láti gba ẹ̀kọ́,+ kí a lè ní ìrètí+ nípasẹ̀ ìfaradà+ wa àti nípasẹ̀ ìtùnú látinú Ìwé Mímọ́.