Sáàmù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+
4 Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Ìtẹ́ Jèhófà wà ní ọ̀run.+ Ojú rẹ̀ ń wò, ojú rẹ̀ tó rí ohun gbogbo* ń ṣàyẹ̀wò àwọn ọmọ èèyàn.+