Ẹ́kísódù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+ Àwọn Onídàájọ́ 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run.
18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+
4 Jèhófà, nígbà tí o jáde ní Séírì,+Nígbà tí o kúrò ní ilẹ̀ Édómù,Ayé mì tìtì, omi ọ̀run sì ya,Omi ya bolẹ̀ látojú ọ̀run.