Sáàmù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìbẹ̀rù Jèhófà+ mọ́, ó wà títí láé. Àwọn ìdájọ́ Jèhófà jẹ́ òótọ́, òdodo ni wọ́n látòkè délẹ̀.+ Sáàmù 119:75 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 75 Jèhófà, mo mọ̀ pé àwọn ìdájọ́ rẹ jẹ́ òdodo+Àti pé nínú òtítọ́ rẹ ni o fìyà jẹ mí.+