Sáàmù 91:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 91 Ẹni tó bá ń gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ+Yóò máa gbé lábẹ́ òjìji Olódùmarè.+ Àìsáyà 25:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí o ti di ibi ààbò fún ẹni rírẹlẹ̀,Ibi ààbò fún aláìní nínú ìdààmú rẹ̀,+Ibi ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì òjò,Àti ibòji kúrò lọ́wọ́ ooru.+ Nígbà tí atẹ́gùn líle àwọn ìkà bá dà bí ìjì òjò tó kọ lu ògiri,
4 Torí o ti di ibi ààbò fún ẹni rírẹlẹ̀,Ibi ààbò fún aláìní nínú ìdààmú rẹ̀,+Ibi ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì òjò,Àti ibòji kúrò lọ́wọ́ ooru.+ Nígbà tí atẹ́gùn líle àwọn ìkà bá dà bí ìjì òjò tó kọ lu ògiri,