-
Sáàmù 115:4-8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àwọn òrìṣà wọn jẹ́ fàdákà àti wúrà,
Iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+
-
-
1 Kọ́ríńtì 10:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí ni mo wá ń sọ? Ṣé pé ohun tí a fi rúbọ sí òrìṣà jẹ́ nǹkan kan tàbí pé òrìṣà jẹ́ nǹkan kan ni?
-