ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà náà, mo sọ fún ọba pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn! Báwo ni ojú mi ò ṣe ní fà ro nígbà tí ìlú tí wọ́n sin àwọn baba ńlá mi sí ti di àwókù, tí iná sì ti jó àwọn ẹnubodè rẹ̀?”+

  • Sáàmù 84:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Àárò ń sọ mí,*

      Àní, àárẹ̀ ti mú mi bó ṣe ń wù mí

      Láti wá sí àwọn àgbàlá Jèhófà.+

      Gbogbo ọkàn àti gbogbo ara mi ni mo fi ń kígbe ayọ̀ sí Ọlọ́run alààyè.

  • Sáàmù 102:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+

      Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+

      Àkókò tí a dá ti pé.+

      14 Nítorí àwọn ìránṣẹ́ rẹ fẹ́ràn àwọn òkúta rẹ̀,+

      Kódà, wọ́n nífẹ̀ẹ́ erùpẹ̀ rẹ̀.+

  • Àìsáyà 62:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 62 Mi ò ní dákẹ́ torí Síónì,+

      Mi ò sì ní dúró jẹ́ẹ́ nítorí Jerúsálẹ́mù,

      Títí òdodo rẹ̀ fi máa tàn bí iná tó mọ́lẹ̀ yòò,+

      Tí ìgbàlà rẹ̀ sì máa jó bí iná ògùṣọ̀.+

  • Jeremáyà 51:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 “Ẹ̀yin tí ẹ bọ́ lọ́wọ́ idà, ẹ máa sá lọ, ẹ má ṣe dúró!+

      Ẹ rántí Jèhófà láti ibi tó jìnnà,

      Kí ẹ sì máa ronú nípa Jerúsálẹ́mù.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́