-
Sáàmù 22:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ìwọ ni Ó gbé mi jáde láti inú ìyá mi,+
Ìwọ ni O mú kí ọkàn mi balẹ̀ ní àyà ìyá mi.
-
-
Sáàmù 71:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìwọ ni mo gbára lé láti ìgbà tí wọ́n ti bí mi;
Ìwọ ló gbé mi jáde látinú ìyá mi.+
Gbogbo ìgbà ni mò ń yìn ọ́.
-
-
Jeremáyà 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Mo fi ọ́ ṣe wòlíì àwọn orílẹ̀-èdè.”
-