-
Sáàmù 18:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Ó ń gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi tí inú ń bí;
Ìwọ gbé mi lékè àwọn tó ń gbéjà kò mí;+
O gbà mí lọ́wọ́ oníwà ipá.
-
48 Ó ń gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi tí inú ń bí;
Ìwọ gbé mi lékè àwọn tó ń gbéjà kò mí;+
O gbà mí lọ́wọ́ oníwà ipá.