Sáàmù 33:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Aláyọ̀ ni orílẹ̀-èdè tí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run rẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ó ti yàn láti jẹ́ ohun ìní rẹ̀.+ Sáàmù 37:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí a ó mú àwọn ẹni ibi kúrò,+Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà ni yóò jogún ayé.+ Sáàmù 37:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+ Sáàmù 146:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Aláyọ̀ ni ẹni tí Ọlọ́run Jékọ́bù jẹ́ olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,+Tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,+
37 Máa fiyè sí aláìlẹ́bi,*Kí o sì máa wo adúróṣinṣin,+Nítorí àlàáfíà ń dúró de ẹni yẹn ní ọjọ́ ọ̀la.+