2 Àwọn Ọba 20:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Pa dà lọ sọ fún Hẹsikáyà aṣáájú àwọn èèyàn mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Dáfídì baba ńlá rẹ sọ nìyí: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ. Mo ti rí omijé rẹ.+ Wò ó, màá mú ọ lára dá.+ Ní ọ̀túnla, wàá lọ sí ilé Jèhófà.+ Sáàmù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n. Sáàmù 103:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó ń dárí gbogbo àṣìṣe mi jì mí,+Ó sì ń wo gbogbo àìsàn mi sàn;+
5 “Pa dà lọ sọ fún Hẹsikáyà aṣáájú àwọn èèyàn mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Dáfídì baba ńlá rẹ sọ nìyí: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ. Mo ti rí omijé rẹ.+ Wò ó, màá mú ọ lára dá.+ Ní ọ̀túnla, wàá lọ sí ilé Jèhófà.+
2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n.