ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 16:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí o ò ní fi mí sílẹ̀* nínú Isà Òkú.*+

      O ò ní jẹ́ kí ẹni ìdúróṣinṣin rẹ rí kòtò.*+

  • Sáàmù 28:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ìwọ ni mò ń ké pè, Jèhófà, Àpáta+ mi;

      Má di etí rẹ sí mi.

      Tí o ò bá dá mi lóhùn,

      Ṣe ni màá dà bí àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*+

  • Àìsáyà 38:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Wò ó! Dípò àlàáfíà, ìbànújẹ́ ńlá ló bá mi;

      Àmọ́ torí ìfẹ́ tí o ní sí mi,*

      O pa mí mọ́ kúrò nínú kòtò ìparun.+

      O ti ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.*+

  • Jónà 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Mo rì wọnú ibú omi lọ sí ìsàlẹ̀ àwọn òkè.

      Ní ti ilẹ̀ ayé, àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀ wà lórí mi títí láé.

      Àmọ́, ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi gbé mi dìde láàyè látinú kòtò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́