-
Sáàmù 17:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn lọ́nà àgbàyanu,+
Ìwọ Olùgbàlà àwọn tó ń wá ààbò ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ
Kí ọwọ́ àwọn tó ń ṣọ̀tẹ̀ sí ọ má bàa tẹ̀ wọ́n.
-
-
Sáàmù 60:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kí a lè gba àwọn olùfẹ́ rẹ sílẹ̀,
Fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbà wá sílẹ̀, kí o sì dá wa lóhùn.+
-