Jóòbù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lẹ́yìn tí Jóòbù gbàdúrà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀,+ Jèhófà mú kí ìpọ́njú Jóòbù kúrò,+ ó sì dá ọlá rẹ̀ pa dà.* Jèhófà fún un ní ìlọ́po méjì ohun tó ní tẹ́lẹ̀.+ Sáàmù 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbogbo ọ̀nà Jèhófà jẹ́ ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́Fún àwọn tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀+ àti àwọn ìránnilétí+ rẹ̀ mọ́.
10 Lẹ́yìn tí Jóòbù gbàdúrà fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀,+ Jèhófà mú kí ìpọ́njú Jóòbù kúrò,+ ó sì dá ọlá rẹ̀ pa dà.* Jèhófà fún un ní ìlọ́po méjì ohun tó ní tẹ́lẹ̀.+
10 Gbogbo ọ̀nà Jèhófà jẹ́ ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́Fún àwọn tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀+ àti àwọn ìránnilétí+ rẹ̀ mọ́.