-
Diutarónómì 7:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 “Tí ẹ bá ń tẹ́tí sí àwọn ìdájọ́ yìí, tí ẹ̀ ń tẹ̀ lé wọn, tí ẹ sì ń pa wọ́n mọ́, Jèhófà Ọlọ́run yín máa pa májẹ̀mú tó bá àwọn baba ńlá yín dá mọ́, ó sì máa fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn bó ṣe ṣèlérí.
-
-
Sáàmù 84:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Jèhófà kò ní fawọ́ ohun rere sẹ́yìn
Lọ́dọ̀ àwọn tó ń rìn nínú ìwà títọ́.+
-