Sáàmù 34:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ bẹ̀rù Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin ẹni mímọ́ rẹ̀,Nítorí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ kò ní ṣaláìní.+ Sáàmù 103:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí bàbá ṣe ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+ Sáàmù 112:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+ Àìsáyà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sọ fún àwọn olódodo pé nǹkan máa lọ dáadáa fún wọn;Wọ́n máa jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.*+ 2 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+
112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+