Sáàmù 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbogbo èèyàn ló mọ̀ pé àwọn ọlọ́gbọ́n pàápàá ń kú;Àwọn òmùgọ̀ àti àwọn aláìnírònú ń ṣègbé pa pọ̀,+Wọ́n á sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún àwọn ẹlòmíì.+ Oníwàásù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo rí gbogbo iṣẹ́ tí a ṣe lábẹ́ ọ̀run,* Sì wò ó! asán ni gbogbo rẹ̀, ìmúlẹ̀mófo.*+ Oníwàásù 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+ 1 Tímótì 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí a ò mú nǹkan kan wá sí ayé, a ò sì lè mú ohunkóhun jáde.+
10 Gbogbo èèyàn ló mọ̀ pé àwọn ọlọ́gbọ́n pàápàá ń kú;Àwọn òmùgọ̀ àti àwọn aláìnírònú ń ṣègbé pa pọ̀,+Wọ́n á sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún àwọn ẹlòmíì.+
16 Nítorí a kì í rántí ọlọ́gbọ́n tàbí òmùgọ̀ títí lọ.+ Bó pẹ́ bó yá, a ò ní rántí ẹnikẹ́ni mọ́. Báwo sì ni ọlọ́gbọ́n ṣe máa kú? Á kú pẹ̀lú àwọn òmùgọ̀.+