Oníwàásù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èrè wo ni èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀ Èyí tó ń fi gbogbo agbára rẹ̀ ṣe lábẹ́ ọ̀run?*+ Oníwàásù 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ayé wá sú mi,+ nítorí gbogbo ohun tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run* ló ń kó ìdààmú báni lójú tèmi, torí asán ni gbogbo rẹ̀,+ ìmúlẹ̀mófo.*+
17 Ayé wá sú mi,+ nítorí gbogbo ohun tí à ń ṣe lábẹ́ ọ̀run* ló ń kó ìdààmú báni lójú tèmi, torí asán ni gbogbo rẹ̀,+ ìmúlẹ̀mófo.*+