-
Diutarónómì 7:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 O ò gbọ́dọ̀ mú ohun ìríra wọnú ilé rẹ, kí o má bàa di ohun tí a máa pa run bí ohun ìríra náà. Kí o kà á sí ẹ̀gbin, kí o sì kórìíra rẹ̀ pátápátá, torí ohun tí a máa pa run ni.
-
-
Sáàmù 115:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àwọn òrìṣà wọn jẹ́ fàdákà àti wúrà,
Iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn.+
-