Jẹ́nẹ́sísì 25:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Orúkọ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì nìyí, orúkọ wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé tí wọ́n ti wá: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+ Àìsáyà 60:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ. Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́. Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+
13 Orúkọ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì nìyí, orúkọ wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé tí wọ́n ti wá: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+
7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ. Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́. Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+