ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 52:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Gbọn eruku kúrò, gbéra kí o sì jókòó, ìwọ Jerúsálẹ́mù.

      Tú ìdè ọrùn rẹ, ìwọ ọmọbìnrin Síónì tí wọ́n mú lẹ́rú.+

  • Jeremáyà 29:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Tó bá ti pé àádọ́rin (70) ọdún tí ẹ ti wà ní Bábílónì, màá yí ojú mi sí yín,+ màá sì mú ìlérí mi ṣẹ láti mú yín pa dà wá sí ibí yìí.’+

  • Jeremáyà 50:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+

      Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+

      Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+

      Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+

      Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+

  • Sekaráyà 9:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ní ti ìwọ obìnrin, nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú rẹ,

      Èmi yóò rán àwọn ẹlẹ́wọ̀n rẹ jáde kúrò nínú kòtò tí kò lómi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́