Jẹ́nẹ́sísì 21:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Lẹ́yìn náà, ó gbin igi támáríkì kan sí Bíá-ṣébà, ó sì ké pe orúkọ Jèhófà,+ Ọlọ́run ayérayé+ níbẹ̀. Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+ Àìsáyà 40:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+ 1 Tímótì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín.
33 Lẹ́yìn náà, ó gbin igi támáríkì kan sí Bíá-ṣébà, ó sì ké pe orúkọ Jèhófà,+ Ọlọ́run ayérayé+ níbẹ̀.
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
28 Ṣé o ò mọ̀ ni? Ṣé o ò tíì gbọ́ ni? Jèhófà, Ẹlẹ́dàá àwọn ìkángun ayé, jẹ́ Ọlọ́run títí ayé.+ Kì í rẹ̀ ẹ́, okun rẹ̀ kì í sì í tán.+ Àwámáridìí ni òye rẹ̀.*+
17 Nítorí náà, kí ọlá àti ògo máa jẹ́ ti Ọba ayérayé,+ ẹni tí kò lè díbàjẹ́,+ tí a kò lè rí,+ Ọlọ́run kan ṣoṣo,+ títí láé àti láéláé. Àmín.