Sáàmù 105:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+ Jeremáyà 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+
10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+
18 “Ní àkókò yẹn, ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì yóò rìn pa pọ̀,+ wọ́n á sì jọ wá láti ilẹ̀ àríwá sí ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín láti jogún.+