Sáàmù 33:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú ẹṣin pé á gbani là* jẹ́ asán;+Agbára ńlá rẹ̀ kò sọ pé kéèyàn yè bọ́. Òwe 21:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Èèyàn lè ṣètò ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun,+Àmọ́ ti Jèhófà ni ìgbàlà.+