Diutarónómì 32:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí àpáta wọn kò dà bí Àpáta+ wa,Àwọn ọ̀tá wa pàápàá ti mọ èyí.+ Diutarónómì 32:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+ Sáàmù 83:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Sáàmù 96:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo ọlọ́run àwọn èèyàn jẹ́ ọlọ́run asán,+Àmọ́ Jèhófà ló dá ọ̀run.+
39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+
18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+