9 Idà àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn ni yóò pa àwọn tó bá dúró nínú ìlú yìí. Àmọ́ ẹni tó bá jáde, tó sì fi ara rẹ̀ lé ọwọ́ àwọn ará Kálídíà tí wọ́n dó tì yín, á máa wà láàyè, á sì jèrè ẹ̀mí rẹ̀.”’*+
6 Wọ́n kó àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin, àwọn ọmọdé àti àwọn ọmọbìnrin ọba, pẹ̀lú gbogbo àwọn* tí Nebusarádánì+ olórí ẹ̀ṣọ́ fi sílẹ̀ sọ́dọ̀ Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì,+ wọ́n sì tún mú wòlíì Jeremáyà àti Bárúkù ọmọ Neráyà.