Àìsáyà 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+ Àìsáyà 47:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ nǹkan méjèèjì yìí máa dé bá ọ lójijì, lọ́jọ́ kan ṣoṣo:+ Wàá ṣòfò ọmọ, wàá sì di opó. Wọ́n máa dé bá ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+Torí* ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ àti gbogbo èèdì rẹ tó lágbára.+ Ìfihàn 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+
9 Wo ohun tó ń bọ̀: Àwọn ọkùnrin wà nínú kẹ̀kẹ́ ogun tí wọ́n so àwọn ẹṣin mọ́!”+ Ó wá sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì ti ṣubú!+ Gbogbo ère gbígbẹ́ àwọn ọlọ́run rẹ̀ ló ti fọ́ sílẹ̀ túútúú!”+
9 Àmọ́ nǹkan méjèèjì yìí máa dé bá ọ lójijì, lọ́jọ́ kan ṣoṣo:+ Wàá ṣòfò ọmọ, wàá sì di opó. Wọ́n máa dé bá ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́,+Torí* ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àjẹ́ rẹ àti gbogbo èèdì rẹ tó lágbára.+
8 Áńgẹ́lì kejì tẹ̀ lé e, ó ń sọ pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá+ ti ṣubú,+ ẹni tó mú kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè mu nínú wáìnì ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́* ti ìṣekúṣe* rẹ̀!”+