Sáàmù 79:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+ Ìdárò 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Elénìní ti kó gbogbo ìṣúra rẹ̀.+ Nítorí ìṣojú rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú ibi mímọ́ rẹ̀,+Àwọn tí o pàṣẹ pé kí wọ́n má ṣe wá sínú ìjọ rẹ.
79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+
10 Elénìní ti kó gbogbo ìṣúra rẹ̀.+ Nítorí ìṣojú rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè wá sínú ibi mímọ́ rẹ̀,+Àwọn tí o pàṣẹ pé kí wọ́n má ṣe wá sínú ìjọ rẹ.