-
Jeremáyà 28:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ní ọdún yẹn kan náà, ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekáyà+ ọba Júdà, ní ọdún kẹrin, ní oṣù karùn-ún, wòlíì Hananáyà ọmọ Ásúrì láti Gíbíónì+ sọ fún mi ní ilé Jèhófà lójú àwọn àlùfáà àti lójú gbogbo àwọn èèyàn náà pé: 2 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Màá ṣẹ́ àjàgà ọba Bábílónì.+
-
-
Jeremáyà 37:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ibo wá ni àwọn wòlíì yín wà, àwọn tó sọ tẹ́lẹ̀ fún yín pé, ‘Ọba Bábílónì kò ní wá gbéjà ko ẹ̀yin àti ilẹ̀ yìí’?+
-