Sáàmù 102:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+ Jeremáyà 33:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+ 7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+
13 Ó dájú pé wàá dìde, wàá sì ṣàánú Síónì,+Torí àkókò ti tó láti ṣe ojú rere sí i;+Àkókò tí a dá ti pé.+
6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+ 7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+