Àìsáyà 51:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+ Àìsáyà 65:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+
3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+
19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+