ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 3:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lọ sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ* tí wọ́n kó lọ sí ìgbèkùn,+ kí o sì bá wọn sọ̀rọ̀. Yálà wọ́n gbọ́ tàbí wọn ò gbọ́, sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí.’”+

  • Ìsíkíẹ́lì 33:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Tí ẹnì kan bá gbọ́ tí ìwo dún àmọ́ tí kò fetí sí ìkìlọ̀,+ tí idà wá, tó sì gba ẹ̀mí rẹ̀,* ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ yóò wà ní ọrùn òun fúnra rẹ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 33:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 tí ẹni burúkú náà wá dá ohun tí wọ́n fi ṣe ìdúró pa dà,+ tó dá àwọn nǹkan tó jí pa dà,+ tó ń hùwà tó dáa láti fi hàn pé òun ń tẹ̀ lé àṣẹ tó ń fúnni ní ìyè, ó dájú pé yóò máa wà láàyè.+ Kò ní kú.

  • Ìsíkíẹ́lì 33:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ó máa ṣẹ, tó bá ti wá ṣẹ, wọ́n á wá mọ̀ pé wòlíì kan ti wà láàárín wọn.”+

  • Jòhánù 15:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ká ní mi ò wá bá wọn sọ̀rọ̀ ni, wọn ò ní ní ẹ̀ṣẹ̀ kankan.+ Àmọ́ ní báyìí, wọn ò ní àwíjàre kankan fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn.+

  • Ìṣe 20:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Torí náà, mo pè yín ṣe ẹlẹ́rìí lónìí yìí pé ọrùn mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ gbogbo èèyàn,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́