Jeremáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Má ṣe jẹ́ kí ìrísí wọn dẹ́rù bà ọ́,+Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ láti gbà ọ́,’+ ni Jèhófà wí.” Ìsíkíẹ́lì 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo ti mú kí iwájú orí rẹ dà bíi dáyámọ́ǹdì, ó le ju akọ òkúta lọ.+ Má bẹ̀rù wọn, má sì jẹ́ kí ojú wọn dẹ́rù bà ọ́,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.”
9 Mo ti mú kí iwájú orí rẹ dà bíi dáyámọ́ǹdì, ó le ju akọ òkúta lọ.+ Má bẹ̀rù wọn, má sì jẹ́ kí ojú wọn dẹ́rù bà ọ́,+ torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.”