Àìsáyà 30:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+ Àìsáyà 51:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+
23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+
3 Torí Jèhófà máa tu Síónì nínú.+ Ó máa tu gbogbo àwókù rẹ̀ nínú,+Ó máa mú kí aginjù rẹ̀ rí bí Édẹ́nì,+Ó sì máa mú kí aṣálẹ̀ rẹ̀ tó tẹ́jú rí bí ọgbà Jèhófà.+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa wà níbẹ̀,Ìdúpẹ́ àti orin tó dùn.+