Ẹ́kísódù 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mósè wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn èèyàn náà,+ ó sì sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá pẹ̀lú gbogbo ọ̀rọ̀ yìí.”+ Léfítíkù 17:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí inú ẹ̀jẹ̀+ ni ẹ̀mí* ẹran wà, èmi fúnra mi sì ti fi sórí pẹpẹ+ fún yín kí ẹ lè ṣe ètùtù fún ara yín,* torí ẹ̀jẹ̀ ló ń ṣe ètùtù+ nípasẹ̀ ẹ̀mí* tó wà nínú rẹ̀. Hébérù 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àní bí Òfin ṣe sọ, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo nǹkan ni wọ́n ń fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀ mọ́,+ ìdáríjì kankan ò sì lè wáyé àfi tí a bá tú ẹ̀jẹ̀ jáde.+
8 Mósè wọ́n ẹ̀jẹ̀ náà sára àwọn èèyàn náà,+ ó sì sọ pé: “Èyí ni ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú tí Jèhófà bá yín dá pẹ̀lú gbogbo ọ̀rọ̀ yìí.”+
11 Torí inú ẹ̀jẹ̀+ ni ẹ̀mí* ẹran wà, èmi fúnra mi sì ti fi sórí pẹpẹ+ fún yín kí ẹ lè ṣe ètùtù fún ara yín,* torí ẹ̀jẹ̀ ló ń ṣe ètùtù+ nípasẹ̀ ẹ̀mí* tó wà nínú rẹ̀.
22 Àní bí Òfin ṣe sọ, ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé gbogbo nǹkan ni wọ́n ń fi ẹ̀jẹ̀ wẹ̀ mọ́,+ ìdáríjì kankan ò sì lè wáyé àfi tí a bá tú ẹ̀jẹ̀ jáde.+