Sáàmù 107:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+ Àìsáyà 55:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òùngbẹ ń gbẹ,+ ẹ wá síbi omi!+ Ẹ̀yin tẹ́ ò ní owó, ẹ wá, ẹ rà, kí ẹ sì jẹ! Àní, ẹ wá, ẹ ra wáìnì àti wàrà+ lọ́fẹ̀ẹ́, láìsan owó.+ Jeremáyà 31:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nítorí ẹni* tí àárẹ̀ mú ni màá tẹ́ lọ́rùn, màá sì pèsè fún gbogbo ẹni* tó jẹ́ aláìní.”+ Mátíù 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Aláyọ̀ ni àwọn tí ebi òdodo ń pa,+ tí òùngbẹ òdodo sì ń gbẹ, torí wọ́n máa yó.*+
9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+
55 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òùngbẹ ń gbẹ,+ ẹ wá síbi omi!+ Ẹ̀yin tẹ́ ò ní owó, ẹ wá, ẹ rà, kí ẹ sì jẹ! Àní, ẹ wá, ẹ ra wáìnì àti wàrà+ lọ́fẹ̀ẹ́, láìsan owó.+