Léfítíkù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà. Mátíù 19:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ+ àti pé, kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+ Róòmù 13:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí àkójọ òfin tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣojúkòkòrò”+ àti àṣẹ míì tó bá wà, ni a kó pọ̀ sínú ọ̀rọ̀ yìí, pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+ Gálátíà 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí a ti mú gbogbo Òfin ṣẹ nínú* àṣẹ kan ṣoṣo, tó sọ pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+ Jémíìsì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Tí ẹ bá ń mú ọba òfin ṣẹ bó ṣe wà nínú ìwé mímọ́ pé, “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ,”+ ẹ̀ ń ṣe dáadáa gan-an ni.
18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà.
9 Nítorí àkójọ òfin tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣojúkòkòrò”+ àti àṣẹ míì tó bá wà, ni a kó pọ̀ sínú ọ̀rọ̀ yìí, pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+
14 Nítorí a ti mú gbogbo Òfin ṣẹ nínú* àṣẹ kan ṣoṣo, tó sọ pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+
8 Tí ẹ bá ń mú ọba òfin ṣẹ bó ṣe wà nínú ìwé mímọ́ pé, “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ,”+ ẹ̀ ń ṣe dáadáa gan-an ni.