Sáàmù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọba ayé dúróÀwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+ Mátíù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó di àárọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa Jésù.+ Máàkù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àwọn akọ̀wé òfin, àní gbogbo Sàhẹ́ndìrìn, gbìmọ̀ pọ̀, wọ́n de Jésù, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́.+ Ìṣe 4:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ọba ayé dúró, àwọn alákòóso sì kóra jọ láti dojú kọ Jèhófà* àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.’+
27 Nígbà tó di àárọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa Jésù.+
15 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà pẹ̀lú àwọn akọ̀wé òfin, àní gbogbo Sàhẹ́ndìrìn, gbìmọ̀ pọ̀, wọ́n de Jésù, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́.+