ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Àwọn ọba ayé dúró

      Àwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+

      Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+

  • Mátíù 27:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nígbà tó di àárọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà gbìmọ̀ pọ̀ kí wọ́n lè pa Jésù.+ 2 Lẹ́yìn tí wọ́n dè é, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fà á lé Pílátù lọ́wọ́, òun ni gómìnà.+

  • Lúùkù 22:66
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 66 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin, kóra jọ,+ wọ́n sì mú un lọ sínú gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn wọn, wọ́n sọ pé:

  • Jòhánù 18:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Wọ́n wá mú Jésù látọ̀dọ̀ Káyáfà lọ sí ilé gómìnà.+ Àárọ̀ kùtù ni. Àmọ́ àwọn fúnra wọn ò wọnú ilé gómìnà, kí wọ́n má bàa sọ ara wọn di aláìmọ́,+ kí wọ́n lè jẹ Ìrékọjá.

  • Ìṣe 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọlọ́run Ábúráhámù àti ti Ísákì àti ti Jékọ́bù,+ Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ti ṣe Jésù,+ Ìránṣẹ́ rẹ̀ lógo,+ ẹni tí ẹ fà lé àwọn èèyàn lọ́wọ́,+ tí ẹ sì sọ níwájú Pílátù pé ẹ ò mọ̀ rí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti pinnu pé òun máa dá a sílẹ̀.

  • Ìṣe 4:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àwọn ọba ayé dúró, àwọn alákòóso sì kóra jọ láti dojú kọ Jèhófà* àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́