Ìṣe 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà. Kólósè 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àrísítákọ́sì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n kí yín, Máàkù+ mọ̀lẹ́bí Bánábà náà kí yín, (ẹni tí a sọ fún yín pé kí ẹ gbà tọwọ́tẹsẹ̀ + tó bá wá sọ́dọ̀ yín), Fílémónì 23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Épáfírásì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n torí Kristi Jésù ń kí ọ, 24 Máàkù, Àrísítákọ́sì,+ Démà+ àti Lúùkù+ tí gbogbo wa jọ ń ṣiṣẹ́ tún kí ọ.
4 Àwọn tó bá a lọ ni Sópátérì ọmọ Párù ará Bèróà, Àrísítákọ́sì+ àti Sẹ́kúńdù láti Tẹsalóníkà, Gáyọ́sì ará Déébè, Tímótì+ pẹ̀lú Tíkíkù+ àti Tírófímù+ láti ìpínlẹ̀ Éṣíà.
10 Àrísítákọ́sì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n kí yín, Máàkù+ mọ̀lẹ́bí Bánábà náà kí yín, (ẹni tí a sọ fún yín pé kí ẹ gbà tọwọ́tẹsẹ̀ + tó bá wá sọ́dọ̀ yín),
23 Épáfírásì+ tí a jọ wà lẹ́wọ̀n torí Kristi Jésù ń kí ọ, 24 Máàkù, Àrísítákọ́sì,+ Démà+ àti Lúùkù+ tí gbogbo wa jọ ń ṣiṣẹ́ tún kí ọ.