Hébérù 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Torí Òfin ò sọ ohunkóhun di pípé,+ àmọ́ ìrètí tó dáa jù+ tó wọlé wá ṣe bẹ́ẹ̀, èyí tí à ń tipasẹ̀ rẹ̀ sún mọ́ Ọlọ́run.+ Hébérù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àgọ́ yìí jẹ́ àpèjúwe fún àkókò yìí,+ a sì ń fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ ní ìbámu pẹ̀lú ètò yìí.+ Àmọ́ àwọn yìí ò lè mú kí ẹni tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ pátápátá.+
19 Torí Òfin ò sọ ohunkóhun di pípé,+ àmọ́ ìrètí tó dáa jù+ tó wọlé wá ṣe bẹ́ẹ̀, èyí tí à ń tipasẹ̀ rẹ̀ sún mọ́ Ọlọ́run.+
9 Àgọ́ yìí jẹ́ àpèjúwe fún àkókò yìí,+ a sì ń fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ ní ìbámu pẹ̀lú ètò yìí.+ Àmọ́ àwọn yìí ò lè mú kí ẹni tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ ní ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ pátápátá.+