2 Orúkọ àwọn àpọ́sítélì méjìlá (12) náà nìyí:+ Àkọ́kọ́, Símónì, tí wọ́n ń pè ní Pétérù+ àti Áńdérù+ arákùnrin rẹ̀; Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù+ arákùnrin rẹ̀;
20 Pétérù yíjú pa dà, ó sì rí ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́+ tó ń tẹ̀ lé e, òun ló fẹ̀yìn ti àyà rẹ̀ níbi oúnjẹ alẹ́, tó sì sọ pé: “Olúwa, ta ló máa dà ọ́?”