ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Wọ́n gbé Àpótí náà sínú àgọ́ (1-6)

      • Orin ìdúpẹ́ tí Dáfídì kọ (7-36)

        • “Jèhófà ti di Ọba!” (31)

      • Iṣẹ́ ìsìn níwájú Àpótí náà (37-43)

1 Kíróníkà 16:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 8:1; 1Kr 15:1
  • +2Sa 6:17-19; 1Ọb 8:5

1 Kíróníkà 16:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 1:3
  • +Le 3:1

1 Kíróníkà 16:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “rántí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 18:2

1 Kíróníkà 16:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aro.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 6:31, 39
  • +1Kr 15:18
  • +1Kr 15:21
  • +1Kr 15:17, 19

1 Kíróníkà 16:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 6:31, 39

1 Kíróníkà 16:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 106:1
  • +Sm 67:2; 105:1-6; Ais 12:4

1 Kíróníkà 16:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọ orin fún un.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “sọ nípa.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 23:1; Ef 5:19
  • +Sm 107:43

1 Kíróníkà 16:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 22:32; Ais 45:25; Jer 9:24
  • +1Kr 28:9; Flp 4:4

1 Kíróníkà 16:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ibi tó wà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 5:4; Sef 2:3
  • +Sm 24:5, 6

1 Kíróníkà 16:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 111:2-4

1 Kíróníkà 16:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àtọmọdọ́mọ.” Ní Héb., “èso.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:8
  • +Sm 135:4

1 Kíróníkà 16:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 95:7
  • +Sm 105:7-11

1 Kíróníkà 16:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọ̀rọ̀ tó pa láṣẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:9

1 Kíróníkà 16:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:18; 17:1, 2
  • +Jẹ 26:3-5

1 Kíróníkà 16:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 28:14

1 Kíróníkà 16:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 12:7; 17:8; 35:12
  • +Di 32:8

1 Kíróníkà 16:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 34:30; Di 26:5; Sm 105:12-15

1 Kíróníkà 16:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 20:1; 46:6

1 Kíróníkà 16:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 31:7, 42
  • +Jẹ 12:17; 20:3

1 Kíróníkà 16:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 20:7

1 Kíróníkà 16:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:10; 96:1-6

1 Kíróníkà 16:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:11

1 Kíróníkà 16:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:20; 1Kọ 8:4
  • +Ais 44:24

1 Kíróníkà 16:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “iyì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:26; Sm 8:1
  • +1Ti 1:11

1 Kíróníkà 16:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 68:34; 96:7-13

1 Kíróníkà 16:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “jọ́sìn.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “nítorí ògo ìjẹ́mímọ́ rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:58; Ne 9:5; Sm 148:13
  • +1Kr 29:3-5; Mt 5:23
  • +Di 26:10

1 Kíróníkà 16:30

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ilẹ̀ tó ń méso jáde.”

  • *

    Tàbí “kò ṣeé mì; a kì yóò mú kó ta gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 104:5; Onw 1:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2005, ojú ìwé 10-11

1 Kíróníkà 16:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 97:1
  • +Ifi 19:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2014, ojú ìwé 10-11

1 Kíróníkà 16:33

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ó ti dé láti.”

1 Kíróníkà 16:34

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 5:13; Lk 18:19
  • +Sm 103:17; Jer 31:3; Ida 3:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2002, ojú ìwé 11

1 Kíróníkà 16:35

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yọ̀ nínú ìyìn rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 68:20
  • +Sm 122:4
  • +Ais 43:21

1 Kíróníkà 16:36

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Láti ayérayé dé ayérayé.”

  • *

    Tàbí “Kó rí bẹ́ẹ̀!”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 9

1 Kíróníkà 16:37

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 15:16, 17
  • +1Kr 16:4-6
  • +Ẹk 29:38; 2Kr 13:11; Ẹsr 3:4

1 Kíróníkà 16:39

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 12:28
  • +1Ọb 3:4

1 Kíróníkà 16:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 29:39; 2Kr 2:4

1 Kíróníkà 16:41

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 25:1
  • +1Kr 16:4
  • +2Kr 5:13; Ẹsr 3:11

1 Kíróníkà 16:42

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kọrin sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 6:31, 33; 15:16, 17
  • +1Kr 25:1, 3

Àwọn míì

1 Kíró. 16:11Ọb 8:1; 1Kr 15:1
1 Kíró. 16:12Sa 6:17-19; 1Ọb 8:5
1 Kíró. 16:2Le 1:3
1 Kíró. 16:2Le 3:1
1 Kíró. 16:4Nọ 18:2
1 Kíró. 16:51Kr 6:31, 39
1 Kíró. 16:51Kr 15:18
1 Kíró. 16:51Kr 15:21
1 Kíró. 16:51Kr 15:17, 19
1 Kíró. 16:71Kr 6:31, 39
1 Kíró. 16:8Sm 106:1
1 Kíró. 16:8Sm 67:2; 105:1-6; Ais 12:4
1 Kíró. 16:92Sa 23:1; Ef 5:19
1 Kíró. 16:9Sm 107:43
1 Kíró. 16:10Le 22:32; Ais 45:25; Jer 9:24
1 Kíró. 16:101Kr 28:9; Flp 4:4
1 Kíró. 16:11Emọ 5:4; Sef 2:3
1 Kíró. 16:11Sm 24:5, 6
1 Kíró. 16:12Sm 111:2-4
1 Kíró. 16:13Ais 41:8
1 Kíró. 16:13Sm 135:4
1 Kíró. 16:14Sm 95:7
1 Kíró. 16:14Sm 105:7-11
1 Kíró. 16:15Di 7:9
1 Kíró. 16:16Jẹ 15:18; 17:1, 2
1 Kíró. 16:16Jẹ 26:3-5
1 Kíró. 16:17Jẹ 28:14
1 Kíró. 16:18Jẹ 12:7; 17:8; 35:12
1 Kíró. 16:18Di 32:8
1 Kíró. 16:19Jẹ 34:30; Di 26:5; Sm 105:12-15
1 Kíró. 16:20Jẹ 20:1; 46:6
1 Kíró. 16:21Jẹ 31:7, 42
1 Kíró. 16:21Jẹ 12:17; 20:3
1 Kíró. 16:22Jẹ 20:7
1 Kíró. 16:23Sm 40:10; 96:1-6
1 Kíró. 16:25Ẹk 15:11
1 Kíró. 16:26Ais 45:20; 1Kọ 8:4
1 Kíró. 16:26Ais 44:24
1 Kíró. 16:27Di 33:26; Sm 8:1
1 Kíró. 16:271Ti 1:11
1 Kíró. 16:28Sm 68:34; 96:7-13
1 Kíró. 16:29Di 28:58; Ne 9:5; Sm 148:13
1 Kíró. 16:291Kr 29:3-5; Mt 5:23
1 Kíró. 16:29Di 26:10
1 Kíró. 16:30Sm 104:5; Onw 1:4
1 Kíró. 16:31Sm 97:1
1 Kíró. 16:31Ifi 19:6
1 Kíró. 16:342Kr 5:13; Lk 18:19
1 Kíró. 16:34Sm 103:17; Jer 31:3; Ida 3:22
1 Kíró. 16:35Sm 68:20
1 Kíró. 16:35Sm 122:4
1 Kíró. 16:35Ais 43:21
1 Kíró. 16:371Kr 15:16, 17
1 Kíró. 16:371Kr 16:4-6
1 Kíró. 16:37Ẹk 29:38; 2Kr 13:11; Ẹsr 3:4
1 Kíró. 16:391Kr 12:28
1 Kíró. 16:391Ọb 3:4
1 Kíró. 16:40Ẹk 29:39; 2Kr 2:4
1 Kíró. 16:411Kr 25:1
1 Kíró. 16:411Kr 16:4
1 Kíró. 16:412Kr 5:13; Ẹsr 3:11
1 Kíró. 16:421Kr 6:31, 33; 15:16, 17
1 Kíró. 16:421Kr 25:1, 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 16:1-43

Kíróníkà Kìíní

16 Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wọlé, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sí àyè rẹ̀ nínú àgọ́ tí Dáfídì pa fún un;+ wọ́n mú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá síwájú Ọlọ́run tòótọ́.+ 2 Nígbà tí Dáfídì parí rírú àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ náà, ó fi orúkọ Jèhófà súre fún àwọn èèyàn náà. 3 Láfikún sí i, ó pín ìṣù búrẹ́dì ribiti àti ìṣù èso déètì àti ìṣù àjàrà gbígbẹ fún gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ó fún kálukú wọn lọ́kùnrin lóbìnrin. 4 Lẹ́yìn náà, ó yan lára àwọn ọmọ Léfì láti máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí Jèhófà,+ kí wọ́n máa bọlá fún* Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí wọ́n máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, kí wọ́n sì máa yìn ín. 5 Ásáfù+ ni olórí, Sekaráyà ni igbá kejì rẹ̀; Jéélì, Ṣẹ́mírámótì, Jéhíélì, Matitáyà, Élíábù, Bẹnáyà, Obedi-édómù àti Jéélì+ ń ta àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù;+ Ásáfù ń lo síńbálì,*+ 6 Bẹnáyà àti Jáhásíẹ́lì tí wọ́n jẹ́ àlùfáà sì ń fun kàkàkí déédéé níwájú àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́.

7 Ọjọ́ yẹn ni Dáfídì kọ́kọ́ ṣàkọsílẹ̀ orin ìdúpẹ́ kan fún Jèhófà, ó sì ní kí Ásáfù+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ kọ ọ́ pé:

8 “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà,+ ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,

Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+

9 Ẹ kọrin sí i, ẹ fi orin yìn ín,*+

Ẹ máa ronú lórí* gbogbo àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+

10 Ẹ máa fi orúkọ mímọ́+ rẹ̀ yangàn.

Kí ọkàn àwọn tó ń wá Jèhófà máa yọ̀.+

11 Ẹ máa wá Jèhófà+ àti agbára rẹ̀.

Ẹ máa wá ojú rẹ̀* nígbà gbogbo.+

12 Ẹ máa rántí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu tó ti ṣe,+

Àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ tó kéde,

13 Ẹ̀yin ọmọ* Ísírẹ́lì ìránṣẹ́ rẹ̀,+

Ẹ̀yin ọmọ Jékọ́bù, ẹ̀yin àyànfẹ́ rẹ̀.+

14 Òun ni Jèhófà Ọlọ́run wa.+

Àwọn ìdájọ́ rẹ̀ kárí ayé.+

15 Ẹ máa rántí májẹ̀mú rẹ̀ títí láé,

Ẹ máa rántí ìlérí tó ṣe* títí dé ẹgbẹ̀rún ìran,+

16 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+

Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+

17 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bù+

Àti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,

18 Ó ní, ‘Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+

Bí ogún tí a pín fún yín.’+

19 Èyí jẹ́ nígbà tí ẹ kéré níye,

Bẹ́ẹ̀ ni, tí ẹ kéré níye gan-an, tí ẹ sì jẹ́ àjèjì ní ilẹ̀ náà.+

20 Wọ́n ń rìn kiri láti orílẹ̀-èdè dé orílẹ̀-èdè,

Láti ọ̀dọ̀ ìjọba kan dé ọ̀dọ̀ àwọn èèyàn míì.+

21 Kò gbà kí ẹnikẹ́ni ni wọ́n lára,+

Ṣùgbọ́n nítorí wọn, ó bá àwọn ọba wí,+

22 Ó ní, ‘Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,

Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.’+

23 Ẹ kọrin sí Jèhófà, gbogbo ayé!

Ẹ kéde ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́!+

24 Ẹ máa kéde ògo rẹ̀ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,

Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀ láàárín gbogbo àwọn èèyàn.

25 Nítorí pé Jèhófà tóbi, òun sì ni ìyìn yẹ jù lọ.

Ó yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù ju gbogbo ọlọ́run yòókù lọ.+

26 Gbogbo ọlọ́run àwọn èèyàn jẹ́ ọlọ́run asán,+

Àmọ́ Jèhófà ló dá ọ̀run.+

27 Ògo àti ọlá ńlá*+ wà pẹ̀lú rẹ̀;

Agbára àti ìdùnnú wà ní ibi tó ń gbé.+

28 Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i, ẹ̀yin ìdílé gbogbo ayé,

Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i nítorí ògo àti agbára rẹ̀.+

29 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+

Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá síwájú rẹ̀.+

Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.*+

30 Kí jìnnìjìnnì bá yín níwájú rẹ̀, gbogbo ayé!

Ayé* fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in; kò ṣeé ṣí nípò.*+

31 Kí ọ̀run yọ̀, kí inú ayé sì dùn;+

Ẹ kéde láàárín àwọn orílẹ̀-èdè pé: ‘Jèhófà ti di Ọba!’+

32 Kí òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ dún bí ààrá;

Kí àwọn pápá àti gbogbo ohun tó wà lórí wọn máa dunnú.

33 Ní àkókò kan náà, kí àwọn igi igbó kígbe ayọ̀ níwájú Jèhófà,

Nítorí ó ń bọ̀ wá* ṣèdájọ́ ayé.

34 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+

Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

35 Ẹ sọ pé, ‘Gbà wá, ìwọ Ọlọ́run ìgbàlà wa,+

Kó wa jọ, kí o sì gbà wá lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,

Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ+

Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+

36 Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì

Títí láé àti láéláé.’”*

Gbogbo èèyàn sì sọ pé, “Àmín!”* wọ́n sì yin Jèhófà.

37 Lẹ́yìn náà, Dáfídì fi Ásáfù+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ sílẹ̀ níbẹ̀ níwájú àpótí májẹ̀mú Jèhófà kí wọ́n lè máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí+ nígbà gbogbo, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ojoojúmọ́.+ 38 Obedi-édómù àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn méjìdínláàádọ́rin (68) àti Obedi-édómù ọmọ Jédútúnì pẹ̀lú Hósà jẹ́ aṣọ́bodè; 39 Àlùfáà Sádókù+ àti àwọn tí wọ́n jọ jẹ́ àlùfáà wà níwájú àgọ́ ìjọsìn Jèhófà ní ibi gíga tó wà ní Gíbíónì+ 40 láti máa rú àwọn ẹbọ sísun sí Jèhófà lórí pẹpẹ ẹbọ sísun déédéé, ní àárọ̀ àti ní ìrọ̀lẹ́ àti láti máa ṣe gbogbo ohun tó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Jèhófà tó pa láṣẹ fún Ísírẹ́lì.+ 41 Àwọn tó wà pẹ̀lú wọn ni Hémánì àti Jédútúnì+ pẹ̀lú ìyókù àwọn ọkùnrin tí a fi orúkọ yàn láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà,+ nítorí “ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé”;+ 42 Hémánì+ àti Jédútúnì wà pẹ̀lú wọn láti máa fun kàkàkí, láti máa lo síńbálì àti àwọn ohun ìkọrin tí a fi ń yin* Ọlọ́run tòótọ́; àwọn ọmọ Jédútúnì+ sì wà ní ẹnubodè. 43 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn èèyàn lọ sí ilé wọn, Dáfídì sì lọ súre fún agbo ilé rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́